Alade Alade Buhariyu o, Alade Buhariyu Omo Omo Oloto e ki Ishola o. Eyin lo l'Oto eyin lon'Idumota Ojora tiyin loje o eyin lomo Olofin, eyin lo l'elegba, Eyin lo l'elegba tonje Olonilogbo leti omi...
K'ade pe lori, ki bata pe lese.
Congratulations sir.
No comments:
Post a Comment